Oluwaṣeun Raheem to ni aisan kansa fẹẹ iranlọwọ yii.
Ọrọ Yoruba kan lo sọ pe ko si nnkan to to alaafia nile aye yii, nitori ni wọn maa ṣe n gbadura pe ki Ọlọrun ma fi aisan bẹ wa … Read More
Best News Website
Ọrọ Yoruba kan lo sọ pe ko si nnkan to to alaafia nile aye yii, nitori ni wọn maa ṣe n gbadura pe ki Ọlọrun ma fi aisan bẹ wa … Read More
Ajo Eso Asobode eka akoko nipinle Ogun ti kéde awọ́n eru fayawo ti won mú bii: oogun oloro ati awon oja fayawo mii ti Owo ori re je Bilionu mefa … Read More
Awon ẹgbẹ Oselu APC Guusu Yewa ni ki Onorebu Latifat lo joko sile pe Onarebu Bayo Orebiyi ni awon Fe ko soju awon lodun 2027 Bo ti le je pe … Read More
Ẹgbẹ́ àlatìlẹ́yìn pàtàkì kan, ti a mo si Pega and Friends Foundation, ti kéde pé òun ti múra tan lati Ra foomu ti Onorebu. Isikalu Olalekan Abidemi, fẹ́ fi dije … Read More
Kontirola Afeni to n dari Iko awon Asobode leka akoko nipinle Ogun ti sabewo sawon oba to wa lenu bode nipinle ogun. Lara awon Oba to sabewo si Odo won … Read More
Ninu fonran kan ti won fi si ayelujara lojo aiku ni Alhaji Ibrahim Dende Egungbohun to je Oluomo Ile Yewa ti fa oko ti won ti se loso ti aworan … Read More
Ogbeni Ayyagari Subbaraidu to je Adari Ile ise Simenti Dangote to wa nilu ibese ti je ko di mimo pe oun ti n gbe igbese lati riipe idagbasoke ba awon … Read More
Lati Owo Orishabuyi Oluwafemi Ojoru ojokeedogun osu kerin odun egbaa odun o-le merindinlogbon yi ni Ile eko gbogbonise ilaro ti won ti yi oruko re pada si Ile eko Yunifásítì … Read More
Omowe Dokita Mukail Akinde to n dari Ile eko Yunifásítì ti ìmọ̀ ẹ̀rọ ti ìjọba àpapọ̀, Ilaro ti je ko di mimo pe awon ti n sise Lori bi awon … Read More
Gomina ipinle Ogun Omooba Dapo Abiodun ti fa Owo Seneto Solomon Olamilekan Yayi to n soju Iwo-oorun ipinle Ogun kale gege bi eni ti ẹgbẹ oselu APC fa kale lati … Read More